OSPOLY: Alakoso eka ibaraẹnisọrọ, ADEAGBO gba awọn ọmọ ile-iwe tuntun (ND1) ni imọran lati darapo mo igbimo NEB

 By: Oluwatosin Adeboye, Boluwaji Daso



Alakoso ti eka ibaraẹnisọrọ (Mass Communication) ti ile-iwe gbogbo nise ti ilu Iree, Ọgbẹni (Mr) Adeagbo S.A ti gba awon ọmọ ile-iwe tuntun ni imọran lati darapọ mọ igbimọ editorial NAMACOS.


Eyi ni o sọ loni, 19th April, 2023 lakoko ti o n ba awọn ọmọ ile-iwe na sọrọ ni hall 3 eka ibaraenisoro naa, ni koko campus


Gege bi Ogbeni Adeagbo se so, “NEB je egbe eyi ti ati fi idi re mule ninu igbimo ise ikansira eni, osi tun je egbe ti o n dani leko ninu igbimo ise ikansira eni”


Adeagbo salaye wipe gege bi akeko ise ikansira eni, Ohun amuyangan ni lati le mo bi ati-n-ba ara eni soro ati lati dojuko agbajo eniyan, bakannaa igbinmo idani leko NEB yoo ṣe afihan agbara ninu wọn.


sibẹsibẹ, o gba awọn ọmọ ile-iwe na niyanju lati yago fun ipa buburu ninu ile-iwe naa ati ki awon akeko na tun jiroro awọn ẹdun okan wọn fun oun tinutinu tabi si Awọn alaṣẹ NAMACOS ti o ba jẹ eyikeyi.

Comments

Popular posts from this blog

Tragic Auto Crash Claims Life of Prominent Mass Communication Student at Osun State Polytechnic, Iree

OSPOLY Mgt Schedules Date for DPT Third Semester Examination, Urges Students To Pay School Fees

OSPOLY Mgt Directs DPT Students For Counselling, Warns Failure to Comply Attract Sanction