Awọn ọmọ ile-iwe gbogbonise (Ospoly) ní lati Nírètí Ibẹrẹ isé, gege bi awon Alakoso se Paṣẹ fun Oṣiṣẹ Ęka Ile-iwe naa lati bẹrẹ isé ni Ojo Ìségun
By: Boluwaji Daso
Awọn alakoso Ile-ẹkọ giga ti Ipinle Osun, Iree, ti paṣẹ fun awọn oṣiṣẹ èka ile-ękò (Part-Time), awọn agùnbánirò (Corper) ati awọn ọmọ ile-iwe I.T ti ile-ẹkọ naa lati pada si ibi iṣẹ wọn ni ọjọ ìségun (Tuesday), ọjọ kẹjọ, oṣu kẹjọ, ọdun 2023.
Won fi eyi leede ninu iwe àtèjáde ti akòròyìn wa ri gba lojo ajé (Monday), ojo keje, osu kejo, odun 2023, ti Iyaafin F.O Apara fowo si fun Alakoso Agba, awon alakoso ile-eko naa pase fun gbogbo awon osise olukoni ati awon agùnbánirò (corper) ti o wa ni eka ile-èkó naa pada si ibi ise won ni ojo ti a so yii. Won si tęnu mo wipe lai se iyemeji, akoko ìwolé si ibi isé jẹ agogo mejo laaro (8:00am) lakoko ti akoko ìlo sílé jẹ agogo meerin irọlẹ (4:00pm? lojoojumọ.
Àtèjáde naa ka ni kikun ni èdè Gẹẹsi;
“I am directed to inform all Part-Time Staff Members, corpers, I.T students in the Institution
(Permanent/Part-Time) to resume for duties with effect from Tuesday, 8th August, 2023
For the avoidance of doubt, the resumption time is 8:00am while closing time is 4:00pm daily.
“Kindly comply with this directive in your own interest.”
Comments
Post a Comment