Ìwìfunní pàtàkì lorí ìgbèsoke ojú òpó aaye àyèlújárá tí Ilé-iwé gígá gbogbo nise tí ìlú iree ní ìpinle osùn.

Abdullateef Bello





     Àwọn Àlakoso Ilé-iwé oùn náà tí fí àkíyèsí pàtàkì ransẹ latí sọ fùn gbogbo eniyan, osiṣẹ, atí àwọn akẹẹkọọ Ilé-iwé oùn náà wìpé enikánkán onì ní àànfàni latí wole sójú òpó aaye àyèlújárá tí Ilé-iwé oùn náà latí ọjọ abamẹta ọjọ kaárùn-ún oṣu tí a wà yìí ni dede ago mẹwa irọlẹ títí dí ago mẹrin owuro ọjọ aiku ọjọ kẹfa ọdún yìí.

     Eyí lo dí mimo nínu iwé asoyepo labenu tí Ilé-iwé oùn náà tẹ jade ni ọjọ kẹrin oṣu yìí nipase Àlakoso Abiodun O. Oloyede tí ò si bowo lu. Ní itẹsiwaju oro rẹ o sọ wìpé ni akòkò ìgbèsoke ojú ọna abawole ojú òpó aaye àyèlújárá yìí, gbogbo àwọn nkan ẹro to sopo mo aaye àyèlújárá yìí yíò wa ni títípà tí ikànkan ò sí nì ní àànfàni latí siṣẹ.


    Pàápàájúlò ìtojú tó peye tí dí pàtàkì latí rìí dájú wìpé iduroṣinṣin, aabo atí iṣẹ pipe orí ẹro àyèlújárá wá n tẹsiwaju. O tún fí kun wìpé lójú ìwòye ohun tó wà lókè yìí, a kàbàámo ìdàámu èyíkéyìí tó lè ṣẹlẹ.

Comments

Popular posts from this blog

OSPOLY MGT DIRECTS STUDENT TO PAY THEIR SCHOOL FEES

Ospoly Mgt Announces Disengagement of Part-Time Staff

Ospoly Mgt Sets #30,000 Penalty for Late Course Registration