Posts

Showing posts from April, 2025

" NO RECORD OF DEATH, OUR STUDENTS ARE SAFE" OSPOLY REGISTRAR, OLOYEDE REASSURES PARENT ON STUDENT'S SAFETY

Image
 By: Tomiwa Obisesan The Management of Osun State Polytechnic, Iree, have reassured parents and guardians on students' safety following a conflict between two rival groups of students on Tuesday 8th of April,2025. According to the Registrar, Mr. Abiodun Oloyede, "Our campus is calm, and normal administrative and academic activities are in progress. Students are going on with their lectures and other academic engagements, while staffs are going about their administrative duties." However , Oloyede noted that the Anti-Cultism Squad of the Nigeria Police and other security operatives are fully employed to prevent any suspected crisis. "Our students are safe," Oloyede emphasized. "We urge parents and guardians not to entertain any fear, as there is no cause for alarm." Two students who sustained minor injuries during the conflict have been treated and discharged from the school's clinic. The polytechnic's management is working to ensure a peaceful ...

Ìwìfunní pàtàkì lorí ìgbèsoke ojú òpó aaye àyèlújárá tí Ilé-iwé gígá gbogbo nise tí ìlú iree ní ìpinle osùn.

Image
Abdullateef Bello      Àwọn Àlakoso Ilé-iwé oùn náà tí fí àkíyèsí pàtàkì ransẹ latí sọ fùn gbogbo eniyan, osiṣẹ, atí àwọn akẹẹkọọ Ilé-iwé oùn náà wìpé enikánkán onì ní àànfàni latí wole sójú òpó aaye àyèlújárá tí Ilé-iwé oùn náà latí ọjọ abamẹta ọjọ kaárùn-ún oṣu tí a wà yìí ni dede ago mẹwa irọlẹ títí dí ago mẹrin owuro ọjọ aiku ọjọ kẹfa ọdún yìí.      Eyí lo dí mimo nínu iwé asoyepo labenu tí Ilé-iwé oùn náà tẹ jade ni ọjọ kẹrin oṣu yìí nipase Àlakoso Abiodun O. Oloyede tí ò si bowo lu. Ní itẹsiwaju oro rẹ o sọ wìpé ni akòkò ìgbèsoke ojú ọna abawole ojú òpó aaye àyèlújárá yìí, gbogbo àwọn nkan ẹro to sopo mo aaye àyèlújárá yìí yíò wa ni títípà tí ikànkan ò sí nì ní àànfàni latí siṣẹ.     Pàápàájúlò ìtojú tó peye tí dí pàtàkì latí rìí dájú wìpé iduroṣinṣin, aabo atí iṣẹ pipe orí ẹro àyèlújárá wá n tẹsiwaju. O tún fí kun wìpé lójú ìwòye ohun tó wà lókè yìí, a kàbàámo ìdàámu èyíkéyìí tó lè ṣẹlẹ.